Tag Archives: moire nike

There is what you know now and what you will know later

Ko si nkankan pamọ.

O’un to wa ni,

nkan ti Aa mọ n’sin,

ati nkan ti Aa maa mọ.

there is nothing hidden.

there is only,

what you know now,

and what you will know later.

Il n’y a rien de caché.

Il n’y a seulement,

Ce que nous savons maintenant,

Et ce que nous saurons plus tard.

no hay nada oculto

hay solamente

lo que sabemos ahora,

hay lo que sabrámos más tarde.

“See you tonight” your friend

Alejo, Guest, invité, invitado.

“Mo nbọ lati ri ọ ni alẹ”, ọrẹ yin.

Eyi ni ifiranṣẹ t’o wa ba eniyan ẹta to mu wọn ni ibẹru. Ko si ọkan ninu wọn ti o le fi ori lori iṣẹ l’ọwọ nitorina wọn pade fun ounjẹ ọsan. Ipade naa jẹ iri ara ko sọrọ tabi nigbagbogbo. Wọn ko pade lati igba ti wọn jẹ ọmọde, ipade ko le jẹ nkan to dun. Lati sọ otitọ wọn n ko ni nkan pupọ l’aarin wọn mọ. Ṣugbọn wọn ni lati pade, nitori ifiranṣẹ ti gbogbo wọn ti gba kii ṣe ifiranṣe ọrẹ tòótọ nigbati-gbati. O jẹ k’ilọ fu awọn mẹta. Pẹlu iranṣẹ yìí aṣiri ti wọn ti bora le ma tu , wa gba awọn mẹta ninu nkan buburu.

“I’m coming to see you tonight” signed, your friend.

This was the message that had three people anxious and afraid. Not one of them could concentrate on work so they met up for lunch. The meeting was awkward as always. They had not met up since they were teenagers, it was to be expected. To tell the truth they didn’t really have much in common in their present lives. But they had to meet, because the message each had received was not a friendly note from a long lost friend. It was a threat that would uncover a secret each had hoped would never be uncovered.

« Je viens te voir ce soir » signé, ton ami.

C’était le message qui avait inquiété et effrayé trois personnes. Aucun d’entre eux ne pouvait se concentrer sur son travail, alors ils se sont retrouvés pour le déjeuner. La rencontre a été délicate comme toujours. Ils ne s’étaient pas rencontrés depuis l’adolescence; il fallait s’y attendre. À vrai dire, ils n’avaient pas grand-chose en commun dans leur vie actuelle. Mais ils devaient se rencontrer, car le message que chacun avait reçu n’était pas une note amicale d’un ami perdu depuis longtemps. C’était une menace qui révélerait un secret que chacun espérait ne jamais être découvert.

“Vengo a verte esta noche”, firmó tu amigo.

Este fue el mensaje que tuvo a tres personas ansiosos y asustados. Ninguno de ellos podía concentrarse en el trabajo, así que se reunieron para almorzar. La reunión fue incómoda como siempre. No se habían visto desde que eran adolescentes; era de esperar. A decir verdad, no tenían mucho en común en su vida actual. Pero tenían que encontrarse, porque el mensaje que cada uno había recibido no era una nota amistosa de un amigo perdido hace mucho tiempo. Era una amenaza que revelaría un secreto que todos habían esperado que nunca fuera descubierto.

If you can’t swim, paddle

Ni aye yii O ma ri nkan to ma di ọna nigbagbogbo. Ti o ba ri odo n’la. O ṣi le wọ ninu kọja. O ṣi le fi ọkọ kọja. L’agbara Olodumare o ṣi le lọ-pada wa.

You will always come up against obstacles in life. You can still swim across a great river, you can still paddle across and you can return.

Usted siempre se encontrará con obstáculos en la vida. Usted todavía puede nadar a través de un gran río, todavía se puede remar a través y se puede volver.

Vous rencontrerez toujours des obstacles dans la vie. Vous pouvez toujours nager à travers une grande rivière, vous pouvez toujours pagayer à travers et vous pouvez revenir.

The breakfast sandwich

Jẹun ti tun ṣe ẹyin ati ẹran l’aarin sabo. Mmmm.

Jeun has done it again the breakfast sandwich with egg and sausage.

Jeun lo ha hecho de nuevo el sándwich de desayuno con huevo y salchicha. delicioso.

Jeun a fait à nouveau le petit déjeuner sandwich avec oeuf et saucisse. miam

Ran me l’ọwọ. Helping Hand

Wọle ṣẹṣẹ de si Eko tuntun. Ile itaja aṣo asiko ko kin taja. O ti fẹ ko itaja si’lẹ, sugbọn o pade Simi. Simi ni ifẹ fun apẹẹrẹ aṣọ, o ṣi ni nkan nla ti o fẹ ṣe. O fẹ ṣe aṣọ gbigbona fun ilu Parisi ni ijọ Iwọ asọ ose aṣọ.Ni aarin awọn meji, iranlọwọ ma mu wọn de oke nini Eko tuntun.

Wole has just arrived in New Eko. His new fashion shop is failing. He is about to give up when he meets Simi. Simi is an aspiring fashion designer with big ideas. Her dream is to headline at Paris Fashion week. With each helping the other they will take over New Eko’s fashion world.

Wole acaba de llegar a New Eko. Su nueva tienda de moda está fallando. está a punto de renunciar cuando conoce a Simi.. Simi es una aspirante a diseñadora de moda con grandes ideas. Su sueño es ser titular en la Semana de la Moda de París. Con cada uno ayudando al otro, tomarán el control del mundo de la moda de Nuevo Eko. 

Wole vient d’arriver à New Eko. Son nouveau magasin de mode est en faillite. Il est sur le point d’abandonner quand il rencontre Simi.. Simi est une créatrice de mode en herbe avec de grandes idées. Son rêve est d’être un démarreur dans la semaine de la mode de Paris . Chacun aidant l’autre, ils domineront le monde de la mode de Nouveau Eko.