Category Archives: fiction

“See you tonight” your friend

Alejo, Guest, invité, invitado.

“Mo nbọ lati ri ọ ni alẹ”, ọrẹ yin.

Eyi ni ifiranṣẹ t’o wa ba eniyan ẹta to mu wọn ni ibẹru. Ko si ọkan ninu wọn ti o le fi ori lori iṣẹ l’ọwọ nitorina wọn pade fun ounjẹ ọsan. Ipade naa jẹ iri ara ko sọrọ tabi nigbagbogbo. Wọn ko pade lati igba ti wọn jẹ ọmọde, ipade ko le jẹ nkan to dun. Lati sọ otitọ wọn n ko ni nkan pupọ l’aarin wọn mọ. Ṣugbọn wọn ni lati pade, nitori ifiranṣẹ ti gbogbo wọn ti gba kii ṣe ifiranṣe ọrẹ tòótọ nigbati-gbati. O jẹ k’ilọ fu awọn mẹta. Pẹlu iranṣẹ yìí aṣiri ti wọn ti bora le ma tu , wa gba awọn mẹta ninu nkan buburu.

“I’m coming to see you tonight” signed, your friend.

This was the message that had three people anxious and afraid. Not one of them could concentrate on work so they met up for lunch. The meeting was awkward as always. They had not met up since they were teenagers, it was to be expected. To tell the truth they didn’t really have much in common in their present lives. But they had to meet, because the message each had received was not a friendly note from a long lost friend. It was a threat that would uncover a secret each had hoped would never be uncovered.

« Je viens te voir ce soir » signé, ton ami.

C’était le message qui avait inquiété et effrayé trois personnes. Aucun d’entre eux ne pouvait se concentrer sur son travail, alors ils se sont retrouvés pour le déjeuner. La rencontre a été délicate comme toujours. Ils ne s’étaient pas rencontrés depuis l’adolescence; il fallait s’y attendre. À vrai dire, ils n’avaient pas grand-chose en commun dans leur vie actuelle. Mais ils devaient se rencontrer, car le message que chacun avait reçu n’était pas une note amicale d’un ami perdu depuis longtemps. C’était une menace qui révélerait un secret que chacun espérait ne jamais être découvert.

“Vengo a verte esta noche”, firmó tu amigo.

Este fue el mensaje que tuvo a tres personas ansiosos y asustados. Ninguno de ellos podía concentrarse en el trabajo, así que se reunieron para almorzar. La reunión fue incómoda como siempre. No se habían visto desde que eran adolescentes; era de esperar. A decir verdad, no tenían mucho en común en su vida actual. Pero tenían que encontrarse, porque el mensaje que cada uno había recibido no era una nota amistosa de un amigo perdido hace mucho tiempo. Era una amenaza que revelaría un secreto que todos habían esperado que nunca fuera descubierto.

Egungun Laide and Tunde

Tunde jẹ ọkunrin to ni ayọ pupọ lara. O ṣi ni nkan pupọ lati ṣe ninu aiye yii. Ṣugbọn l’ẹhin iwa ninu ọkọ ni ọjọbọ, nkan ajeji n ṣẹlẹ. Iya ko ba sọrọ mọ, n kọ mọ nkan to fa.

Laide jẹ Iya-ajẹ n gbangba. O n ṣe iranlọwọ fun eniyan pẹlu nkan ṣoro ni aiye pẹlu emi buburu ti a o le ri. O ṣe Oogun aabo; o ṣi le ri nkan bora fun eniyan.

Laide wa ba Tunde l’aarin iṣẹ abọ. Ni akoko o mọ pe Tunde ti ku, di iwin. Ṣe Laide le ran tunde l’ọwọ ba ri ẹbi wọn?

Tunde is a man with his whole life ahead of him. But since his car ride on Wednesday he feels strange. His mother keeps ignoring him and he does not know why.

Laide is a professional witch. She helps people with their spiritual other world problems. She makes Protection charms and can see the other side of things.

Laide meets Tunde during one of her “Protection jobs”. At once she knows his problem. He is a lost ghost. Can Laide help Tunde connect with his family?

Tunde es un hombre con toda su vida por delante de él. Pero desde su viaje en coche el miércoles se siente extraño. Su madre sigue ignorándolo y él no sabe por qué.

Laide es una bruja profesional. Ella ayuda a las personas con sus otros problemas mundiales espirituales. Ella hace amuletos de protección y puede ver el otro lado de las cosas.

Laide se encuentra con Tunde durante uno de sus “trabajos de protección”. De inmediato ella conoce su problema. Él es un fantasma perdido. ¿Puede Lide Ayudar a Tunde conectarse con su familia?

Tunde est un homme avec toute sa vie devant lui. Mais depuis sa promenade de voiture mercredi, il se sent étrange. Sa mère continue à l’ignorer et il ne sait pas pourquoi.

Laide est une sorcière professionnelle. Elle aide les personnes avec leurs problèmes spirituels d’autres problèmes mondiaux. Elle fait des charmes de protection et peut voir l’autre côté des choses.

Laide rencontre Tunde lors de l’un de ses “emplois de protection”. À la fois, elle connaît son problème. Il est un fantôme perdu. Peut-elle, Laide , aider Tunde Connecter avec sa famille?

Iwadi: Lagos to Accra

DCI Bode and DCI Nike Iwadi Investigations

Ẹnikan kilọ fun Ọga Eko-titun. Ni ọjọ keji laarin ayẹyẹ fun ọkọkọ tuntun lati Eko de Accra, nkan buru. Ibọn nla bẹ́́.

Someone has threatened the Mayor of new Eko. A day later during the launch of the new Lagos to Accra train, there is an explosion.

Alguien ha amenazado al alcalde de Nueva Eko. Un día más tarde, durante el lanzamiento de los nuevos lagos hasta el tren Accra, hay una explosión.

Quelqu’un a menacé le maire de la nouvelle Eko. Un jour plus tard, lors du lancement du nouveau train Lagos jusqu’en Accra, il y a une explosion.

Tani li o ṣe? Nitori kini? DCI Bọde ati Nikẹ wa l’ori iwadi yii.

Who caused the explosion? And why? DCI Bọde and Nikẹ are put on the case.

¿Quién causó la explosión? ¿Y por qué? DCI Bọde y Nikẹ se ponen en el caso.

Qui a causé l’explosion? Et pourquoi? DCI Bọde et Nikẹ sont mis sur le cas.

DCI Bode Iwadi Investigations
DCI Bode and DCI Nike Iwadi Investigations

Two sisters Ẹgbọn Aburo

Blessing and Lovely. Two sisters who are going to achieve their dreams.

Ibukun ati Ifọ. Ẹgbọn Aburo obinrin meji ti yio ṣe gbe alafia.

Bénédiction et Belle. Deux sœurs qui vont réaliser leurs rêves.

Bendición y Bonita. Dos hermanas que van a lograr sus sueños.

Ọrẹ mi gbẹhin. My old friend.

Pẹlu ogún l’ọwọ ọdọ ọrẹ ti o sọda gbẹhin. Boya Jemaimah le ṣe gba ifẹ lati di Aranṣọ. Bayi O ni owo ati iranlọwọ ti ẹmi ọrẹ rẹ Jọọnu. Ṣẹ nkan buru le ṣẹlẹ?

With an inheritance from a long lost friend. Maybe Jemaimah can finally achieve her dream of being a fashion designer. Now she has the money and the support of the spirit of her friend John. What could go wrong?

Con una herencia de un amigo perdido hace mucho tiempo. Quizás Jemaimah finalmente pueda lograr su sueño de ser diseñadora de moda. Ahora tiene el dinero y el apoyo del espíritu de su amigo John. ¿Qué puede salir mal?

Irawọ Oniru: Healing hands

Dáre jẹ obinrin to fẹ nkan pere, aiye igbadun. Ni ọjọ kan Irawọ Oniru ju si ilẹ, O kan Dare lori. Nigba Dare wa ji. O ri pe o ni agbara tuntún. Nisiyi ti o ba fi ọwọ kan eniyan, O ma ṣe iwosan lori; gbogbo ara ma dara. Gbogbo nkan bajẹ ma bẹ jade. Gbogbo abule wa gbọ, nitori yìí wọn fẹ ayọ l’ọwọ Dare. Iya alata, Oni Iran-Aṣọ titi de Ọta ọdun mẹwa gbẹhin. Gbogbo wọn fẹ diẹ ninu ẹbun Dare. Dare ranti fun gbogbo ọjọ gbẹyin to fẹ di eniyan giga. Nisiyi gbogbo ile fẹ. Ṣe o’un naa ni wọn fẹ? Boya agbara l’ọwọ nikan ni wọn fẹ. L’oni Okunrin Olori ile-Igbagbọ wa ba. O sọ pe ọna kan wa fun Dare lati rin. Ona to de Ile-Igbagbọ ti Okunrin yẹn ni, Nitori pe oun laalaa pe, O lati fẹ Dare.

Irawo Oniru

Dare is a woman that wants just one thing, a good life. One day a comet falls to earth and knocks her out. When Dare wakes up, she sees she has a new power. Now when she touches a person, she can heal them. The healing affects the whole body and reverses any injury.Everyone hears and now they want some of this good fortune. The Grocer, the Tailor, even enemies from ten years ago. Everyone wants a little of this gift. Dare remembered all those days she wanted to be famous. Now everyone loves her. But do they love her? Maybe it’s just her power they want. Today a Religious Leader shows up. He makes an offer she cannot refuse. He tells her that he will take her to his congregation, because he had a dream saying he has to marry her.

Dare es una mujer que quiere una sola cosa, una buena vida. Un día, un cometa cae a la tierra y la golpea inconsciente. Cuando Dare se despierta, ve que tiene un nuevo poder. Ahora, cuando toca a una persona, ella puede curarlas. La curación afecta a todo el cuerpo y revierte cualquier lesión. Todos escuchan y ahora quieren algo de esta buena fortuna. El tendero, el sastre, incluso los enemigos de hace diez años. Todos quieren un poco de este regalo. Dare recordó todos los días que quería ser famosa. Ahora todos la aman. ¿Pero ellos la aman? Tal vez sea solo su poder que quieren. Hoy aparece un líder religioso. Él la convierte en una oferta. Él le dice que la llevará a su congregación, porque él tenía un sueño diciéndole que ella es su destino.

Dare est une femme qui veut juste une chose, une bonne vie. Un jour, une comète tombe sur terre et frappe son inconscient. Quand Dare se réveiller, elle voit qu’elle a un nouveau pouvoir. Maintenant, quand elle touche une personne, elle peut les guérir. La guérison affecte tout le corps et inverse toute blessure. Tout le monde entend et maintenant, ils veulent une partie de cette bonne fortune. L’épicier, le tailleur, même des ennemis il y a dix ans. Tout le monde veut un peu de ce cadeau. Ose se souvenir de tous ces jours où elle voulait être célèbre. Maintenant, tout le monde l’aime. Mais aimons-ils? Peut-être que c’est juste son pouvoir qu’ils veulent. Aujourd’hui, un chef religieux apparaît. Il lui fait une offre. Il lui dit qu’il l’emmènera à sa congrégation, car il avait un rêve de lui dire qu’elle est son destin.